Quran with Yoruba translation - Surah Al-Masad ayat 1 - المَسَد - Page - Juz 30
﴿تَبَّتۡ يَدَآ أَبِي لَهَبٖ وَتَبَّ ﴾
[المَسَد: 1]
﴿تبت يدا أبي لهب وتب﴾ [المَسَد: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọwọ́ Abu-Lahab méjèèjì ti ṣòfò. Òun náà sì ṣòfò |