Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘adiyat ayat 3 - العَاديَات - Page - Juz 30
﴿فَٱلۡمُغِيرَٰتِ صُبۡحٗا ﴾
[العَاديَات: 3]
﴿فالمغيرات صبحا﴾ [العَاديَات: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún búra pẹ̀lú àwọn ẹṣin t’ó ń kọlu ọ̀tá ẹ̀sìn ní òwúrọ̀ kùtùkùtù |