القرآن باللغة اليوربا - سورة العاديات مترجمة إلى اللغة اليوربا، Surah Adiyat in Yoruba. نوفر ترجمة دقيقة سورة العاديات باللغة اليوربا - Yoruba, الآيات 11 - رقم السورة 100 - الصفحة 599.
وَالْعَادِيَاتِ ضَبْحًا (1) Allahu bura pelu awon esin t’o n sare t’o n mi helehele ni oju-ogun |
فَالْمُورِيَاتِ قَدْحًا (2) O tun bura pelu awon esin ti patako ese won n sana (nibi ere sisa) |
فَالْمُغِيرَاتِ صُبْحًا (3) O tun bura pelu awon esin t’o n kolu ota esin ni owuro kutukutu |
فَأَثَرْنَ بِهِ نَقْعًا (4) Won si fi (patako ese won) tu eruku (ile ota) soke |
فَوَسَطْنَ بِهِ جَمْعًا (5) Won tun be gija papo pelu re saaarin akojo ota |
إِنَّ الْإِنسَانَ لِرَبِّهِ لَكَنُودٌ (6) Dajudaju eniyan ni alaimoore si Oluwa re |
وَإِنَّهُ عَلَىٰ ذَٰلِكَ لَشَهِيدٌ (7) Dajudaju Allahu si n je Elerii lori iyen |
وَإِنَّهُ لِحُبِّ الْخَيْرِ لَشَدِيدٌ (8) Ati pe dajudaju eniyan le gan-an nibi ife oore aye |
۞ أَفَلَا يَعْلَمُ إِذَا بُعْثِرَ مَا فِي الْقُبُورِ (9) Se ko mo pe nigba ti won ba tu ohun t’o wa ninu saree jade (fun ajinde) |
وَحُصِّلَ مَا فِي الصُّدُورِ (10) ti won si tu ohun t’o wa ninu igba-aya eda sita patapata |
إِنَّ رَبَّهُم بِهِمْ يَوْمَئِذٍ لَّخَبِيرٌ (11) dajudaju Oluwa won ni Alamotan nipa won ni Ojo yen |