Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘adiyat ayat 2 - العَاديَات - Page - Juz 30
﴿فَٱلۡمُورِيَٰتِ قَدۡحٗا ﴾ 
[العَاديَات: 2]
﴿فالموريات قدحا﴾ [العَاديَات: 2]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún búra pẹ̀lú àwọn ẹṣin tí pátákò ẹsẹ̀ wọn ń ṣáná (níbi eré sísá) |