Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 1 - يُوسُف - Page - Juz 12
﴿الٓرۚ تِلۡكَ ءَايَٰتُ ٱلۡكِتَٰبِ ٱلۡمُبِينِ ﴾
[يُوسُف: 1]
﴿الر تلك آيات الكتاب المبين﴾ [يُوسُف: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni ’Alif lām rọ̄. Ìwọ̀nyí ni àwọn āyah Tírà t’ó yanjú ọ̀rọ̀ ẹ̀dá |