Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 2 - يُوسُف - Page - Juz 12
﴿إِنَّآ أَنزَلۡنَٰهُ قُرۡءَٰنًا عَرَبِيّٗا لَّعَلَّكُمۡ تَعۡقِلُونَ ﴾
[يُوسُف: 2]
﴿إنا أنـزلناه قرآنا عربيا لعلكم تعقلون﴾ [يُوسُف: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa sọ̀ ọ́ kalẹ̀ ní n̄ǹkan kíké ní èdè Lárúbáwá nítorí kí ẹ lè ṣe làákàyè |