Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 53 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَوَهَبۡنَا لَهُۥ مِن رَّحۡمَتِنَآ أَخَاهُ هَٰرُونَ نَبِيّٗا ﴾
[مَريَم: 53]
﴿ووهبنا له من رحمتنا أخاه هارون نبيا﴾ [مَريَم: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Láti inú ìkẹ́ Wa A sì fi arákùnrin rẹ̀, Hārūn, (tí ó jẹ́) Ànábì, ta á lọ́rẹ |