Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 52 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَنَٰدَيۡنَٰهُ مِن جَانِبِ ٱلطُّورِ ٱلۡأَيۡمَنِ وَقَرَّبۡنَٰهُ نَجِيّٗا ﴾
[مَريَم: 52]
﴿وناديناه من جانب الطور الأيمن وقربناه نجيا﴾ [مَريَم: 52]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A pè é ní ẹ̀bá àpáta ní apá ọwọ́ ọ̀tún (Mūsā). A sì mú un súnmọ́ tòsí láti bá a sọ̀rọ̀ |