Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 147 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿ٱلۡحَقُّ مِن رَّبِّكَ فَلَا تَكُونَنَّ مِنَ ٱلۡمُمۡتَرِينَ ﴾
[البَقَرَة: 147]
﴿الحق من ربك فلا تكونن من الممترين﴾ [البَقَرَة: 147]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òdodo náà wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ. Nítorí náà, o ò gbọdọ̀ wà lára àwọn oníyèméjì |