Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 78 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿ٱلَّذِي خَلَقَنِي فَهُوَ يَهۡدِينِ ﴾
[الشعراء: 78]
﴿الذي خلقني فهو يهدين﴾ [الشعراء: 78]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Òun ni) Ẹni tí Ó ṣẹ̀dá mi. Nítorí náà, Ó máa fi ọ̀nà mọ̀ mí |