Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 77 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَإِنَّهُمۡ عَدُوّٞ لِّيٓ إِلَّا رَبَّ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الشعراء: 77]
﴿فإنهم عدو لي إلا رب العالمين﴾ [الشعراء: 77]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn ni ọ̀tá fún mi àyàfi Olúwa gbogbo ẹ̀dá |