Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 150 - آل عِمران - Page - Juz 4
﴿بَلِ ٱللَّهُ مَوۡلَىٰكُمۡۖ وَهُوَ خَيۡرُ ٱلنَّٰصِرِينَ ﴾
[آل عِمران: 150]
﴿بل الله مولاكم وهو خير الناصرين﴾ [آل عِمران: 150]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu sì ni Alárànṣe yín. Ó sì lóore jùlọ nínú àwọn alárànṣe |