Quran with Yoruba translation - Surah Saba’ ayat 29 - سَبإ - Page - Juz 22
﴿وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا ٱلۡوَعۡدُ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ ﴾
[سَبإ: 29]
﴿ويقولون متى هذا الوعد إن كنتم صادقين﴾ [سَبإ: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sì ń wí pé: “Ìgbà wo ni àdéhùn yìí yóò ṣẹ tí ẹ bá jẹ́ olódodo?” |