Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 122 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿إِنَّهُمَا مِنۡ عِبَادِنَا ٱلۡمُؤۡمِنِينَ ﴾
[الصَّافَات: 122]
﴿إنهما من عبادنا المؤمنين﴾ [الصَّافَات: 122]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn méjèèjì wà nínú àwọn ẹrúsìn Wa, àwọn onígbàgbọ́ òdodo |