Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 66 - الزُّمَر - Page - Juz 24
﴿بَلِ ٱللَّهَ فَٱعۡبُدۡ وَكُن مِّنَ ٱلشَّٰكِرِينَ ﴾
[الزُّمَر: 66]
﴿بل الله فاعبد وكن من الشاكرين﴾ [الزُّمَر: 66]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Rárá (má ṣẹbọ). Allāhu nìkan ni kí o jọ́sìn fún. Kí o sì wà nínú àwọn olùdúpẹ́ (fún Un) |