Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 79 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿ٱللَّهُ ٱلَّذِي جَعَلَ لَكُمُ ٱلۡأَنۡعَٰمَ لِتَرۡكَبُواْ مِنۡهَا وَمِنۡهَا تَأۡكُلُونَ ﴾
[غَافِر: 79]
﴿الله الذي جعل لكم الأنعام لتركبوا منها ومنها تأكلون﴾ [غَافِر: 79]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu ni Ẹni tí Ó dá àwọn ẹran-ọ̀sìn fun yín nítorí kí ẹ lè máa gùn nínú wọn. Ẹ ó sì máa jẹ nínú wọn |