Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma’idah ayat 98 - المَائدة - Page - Juz 7
﴿ٱعۡلَمُوٓاْ أَنَّ ٱللَّهَ شَدِيدُ ٱلۡعِقَابِ وَأَنَّ ٱللَّهَ غَفُورٞ رَّحِيمٞ ﴾
[المَائدة: 98]
﴿اعلموا أن الله شديد العقاب وأن الله غفور رحيم﴾ [المَائدة: 98]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ mọ̀ pé dájúdájú Allāhu le níbi ìyà. Àti pé dájúdájú Allāhu ni Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run |