Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma’idah ayat 99 - المَائدة - Page - Juz 7
﴿مَّا عَلَى ٱلرَّسُولِ إِلَّا ٱلۡبَلَٰغُۗ وَٱللَّهُ يَعۡلَمُ مَا تُبۡدُونَ وَمَا تَكۡتُمُونَ ﴾
[المَائدة: 99]
﴿ما على الرسول إلا البلاغ والله يعلم ما تبدون وما تكتمون﴾ [المَائدة: 99]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí ojúṣe kan fún Òjíṣẹ́ náà bí kò ṣe iṣẹ́-jíjẹ́. Allāhu sì mọ ohun tí ẹ̀ ń ṣàfi hàn rẹ̀ àti ohun tí ẹ̀ ń fi pamọ́ |