Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 24 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿هَلۡ أَتَىٰكَ حَدِيثُ ضَيۡفِ إِبۡرَٰهِيمَ ٱلۡمُكۡرَمِينَ ﴾
[الذَّاريَات: 24]
﴿هل أتاك حديث ضيف إبراهيم المكرمين﴾ [الذَّاريَات: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ àwọn àlejò (Ànábì) ’Ibrọ̄hīm, àwọn alápọ̀n-ọ́nlé, ti dé ọ̀dọ̀ rẹ |