Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 25 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿إِذۡ دَخَلُواْ عَلَيۡهِ فَقَالُواْ سَلَٰمٗاۖ قَالَ سَلَٰمٞ قَوۡمٞ مُّنكَرُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 25]
﴿إذ دخلوا عليه فقالوا سلاما قال سلام قوم منكرون﴾ [الذَّاريَات: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí) nígbà tí wọ́n wọlé tọ̀ ọ́ wá, wọ́n sì sọ pé: "Àlàáfíà (fún ọ)." Òun náà sọ pé: "Àlàáfíà (fun yín), ẹ̀yin àjòjì ènìyàn |