Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 41 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿وَأَصۡحَٰبُ ٱلشِّمَالِ مَآ أَصۡحَٰبُ ٱلشِّمَالِ ﴾
[الوَاقِعة: 41]
﴿وأصحاب الشمال ما أصحاب الشمال﴾ [الوَاقِعة: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn èrò ọwọ́ òsì, kí ni (ó máa ti burú tó fún) àwọn èrò ọwọ́ òsì |