Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 32 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿ثُمَّ فِي سِلۡسِلَةٖ ذَرۡعُهَا سَبۡعُونَ ذِرَاعٗا فَٱسۡلُكُوهُ ﴾
[الحَاقة: 32]
﴿ثم في سلسلة ذرعها سبعون ذراعا فاسلكوه﴾ [الحَاقة: 32]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, inú ẹ̀wọ̀n tí gígùn rẹ̀ jẹ́ àádọ́rin gígùn thar‘u ni kí ẹ kì í sí |