Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qiyamah ayat 19 - القِيَامة - Page - Juz 29
﴿ثُمَّ إِنَّ عَلَيۡنَا بَيَانَهُۥ ﴾
[القِيَامة: 19]
﴿ثم إن علينا بيانه﴾ [القِيَامة: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, dájúdájú Àwa l’A máa ṣe àlàyé rẹ̀ fún ọ |