Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mursalat ayat 1 - المُرسَلات - Page - Juz 29
﴿وَٱلۡمُرۡسَلَٰتِ عُرۡفٗا ﴾
[المُرسَلات: 1]
﴿والمرسلات عرفا﴾ [المُرسَلات: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu búra pẹ̀lú àwọn atẹ́gùn t’ó ń sáré ní tẹ̀léǹtẹ̀lé |