×

Surah Al-Mursalat in Yoruba

Quran Yoruba ⮕ Surah Mursalat

Translation of the Meanings of Surah Mursalat in Yoruba - اليوربا

The Quran in Yoruba - Surah Mursalat translated into Yoruba, Surah Al-Mursalat in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Mursalat in Yoruba - اليوربا, Verses 50 - Surah Number 77 - Page 580.

بسم الله الرحمن الرحيم

وَالْمُرْسَلَاتِ عُرْفًا (1)
Allahu bura pelu awon ategun t’o n sare ni telentele
فَالْعَاصِفَاتِ عَصْفًا (2)
O bura pelu awon iji ategun t’o n ja
وَالنَّاشِرَاتِ نَشْرًا (3)
O bura pelu awon ategun t’o n tu esujo ka
فَالْفَارِقَاتِ فَرْقًا (4)
O bura pelu awon t’o n sepinya laaarin ododo ati iro
فَالْمُلْقِيَاتِ ذِكْرًا (5)
O tun bura pelu awon molaika t’o n mu iranti wa (ba awon Ojise)
عُذْرًا أَوْ نُذْرًا (6)
(Iranti naa je) awijare tabi ikilo
إِنَّمَا تُوعَدُونَ لَوَاقِعٌ (7)
Dajudaju ohun ti A se ni adehun fun yin kuku maa sele
فَإِذَا النُّجُومُ طُمِسَتْ (8)
Nitori naa, nigba ti won ba pa (imole) irawo re
وَإِذَا السَّمَاءُ فُرِجَتْ (9)
ati nigba ti won ba si sanmo sile gbagada
وَإِذَا الْجِبَالُ نُسِفَتْ (10)
ati nigba ti won ba ku awon apata danu
وَإِذَا الرُّسُلُ أُقِّتَتْ (11)
ati nigba ti won ba fun awon Ojise ni asiko lati kojo, (Akoko naa ti de niyen)
لِأَيِّ يَوْمٍ أُجِّلَتْ (12)
Ojo wo ni won so (awon isele wonyi) ro fun na
لِيَوْمِ الْفَصْلِ (13)
Fun ojo ipinya (laaarin awon eda) ni
وَمَا أَدْرَاكَ مَا يَوْمُ الْفَصْلِ (14)
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Ojo ipinya
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (15)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
أَلَمْ نُهْلِكِ الْأَوَّلِينَ (16)
Nje Awa ko ti pa awon eni akoko re bi
ثُمَّ نُتْبِعُهُمُ الْآخِرِينَ (17)
Leyin naa, A si maa fi awon eni Ikeyin tele won (ninu iparun)
كَذَٰلِكَ نَفْعَلُ بِالْمُجْرِمِينَ (18)
Bayen ni A o ti se pelu awon elese
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (19)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
أَلَمْ نَخْلُقكُّم مِّن مَّاءٍ مَّهِينٍ (20)
Se A o seda yin lati inu omi lile yepere bi
فَجَعَلْنَاهُ فِي قَرَارٍ مَّكِينٍ (21)
Leyin naa, A fi sinu aye aabo (iyen, ile-omo)
إِلَىٰ قَدَرٍ مَّعْلُومٍ (22)
titi di gbedeke akoko kan ti A ti mo (iyen, ojo ibimo)
فَقَدَرْنَا فَنِعْمَ الْقَادِرُونَ (23)
A si ni ikapa ati ayanmo (lori re). (Awa si ni) Olukapa ati Olupebubu eda t’o dara
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (24)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
أَلَمْ نَجْعَلِ الْأَرْضَ كِفَاتًا (25)
Nje Awa ko se ile ni ohun t’o n ko eda jo mora won
أَحْيَاءً وَأَمْوَاتًا (26)
(iyen) awon alaaye ati awon oku
وَجَعَلْنَا فِيهَا رَوَاسِيَ شَامِخَاتٍ وَأَسْقَيْنَاكُم مَّاءً فُرَاتًا (27)
A si fi awon apata gbagidi giga-giga sinu re. A si fun yin ni omi didun mu
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (28)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
انطَلِقُوا إِلَىٰ مَا كُنتُم بِهِ تُكَذِّبُونَ (29)
E maa lo si ibi ti e n pe niro
انطَلِقُوا إِلَىٰ ظِلٍّ ذِي ثَلَاثِ شُعَبٍ (30)
E maa lo si ibi eefin eleka meta
لَّا ظَلِيلٍ وَلَا يُغْنِي مِنَ اللَّهَبِ (31)
Ki i se iboji tutu. Ko si nii ro won loro ninu ijofofo Ina
إِنَّهَا تَرْمِي بِشَرَرٍ كَالْقَصْرِ (32)
Dajudaju (Ina naa) yoo maa ju etapara (re soke t’o maa da) bi peteesi
كَأَنَّهُ جِمَالَتٌ صُفْرٌ (33)
(O maa da) bi awon rakunmi alawo omi osan
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (34)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
هَٰذَا يَوْمُ لَا يَنطِقُونَ (35)
Eyi ni ojo ti won ko nii soro
وَلَا يُؤْذَنُ لَهُمْ فَيَعْتَذِرُونَ (36)
A o si nii yonda (oro siso) fun won, ambosibosi pe won yoo mu awawi wa
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (37)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
هَٰذَا يَوْمُ الْفَصْلِ ۖ جَمَعْنَاكُمْ وَالْأَوَّلِينَ (38)
Eyi ni ojo ipinya. Awa yo si ko eyin ati awon eni akoko jo
فَإِن كَانَ لَكُمْ كَيْدٌ فَكِيدُونِ (39)
Ti e ba ni ete kan lowo, e dete si Mi wo
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (40)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
إِنَّ الْمُتَّقِينَ فِي ظِلَالٍ وَعُيُونٍ (41)
Dajudaju awon oluberu Allahu yoo wa nibi iboji ati awon omi iseleru
وَفَوَاكِهَ مِمَّا يَشْتَهُونَ (42)
ati awon eso eyi ti won ba n fe
كُلُوا وَاشْرَبُوا هَنِيئًا بِمَا كُنتُمْ تَعْمَلُونَ (43)
E je, ki e si mu pelu igbadun nitori ohun ti e n se nise
إِنَّا كَذَٰلِكَ نَجْزِي الْمُحْسِنِينَ (44)
Dajudaju bayen ni Awa se n san awon oluse-rere ni esan (rere)
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (45)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
كُلُوا وَتَمَتَّعُوا قَلِيلًا إِنَّكُم مُّجْرِمُونَ (46)
E je, ki e si gbadun fun igba die. Dajudaju elese ni yin
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (47)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
وَإِذَا قِيلَ لَهُمُ ارْكَعُوا لَا يَرْكَعُونَ (48)
Nigba ti won ba so fun won pe ki won kirun, won ko nii kirun
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِّلْمُكَذِّبِينَ (49)
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
فَبِأَيِّ حَدِيثٍ بَعْدَهُ يُؤْمِنُونَ (50)
Nigba naa, oro wo ni won yoo gbagbo leyin re
❮ Previous Next ❯

Surahs from Quran :

1- Fatiha2- Baqarah
3- Al Imran4- Nisa
5- Maidah6- Anam
7- Araf8- Anfal
9- Tawbah10- Yunus
11- Hud12- Yusuf
13- Raad14- Ibrahim
15- Hijr16- Nahl
17- Al Isra18- Kahf
19- Maryam20- TaHa
21- Anbiya22- Hajj
23- Muminun24- An Nur
25- Furqan26- Shuara
27- Naml28- Qasas
29- Ankabut30- Rum
31- Luqman32- Sajdah
33- Ahzab34- Saba
35- Fatir36- Yasin
37- Assaaffat38- Sad
39- Zumar40- Ghafir
41- Fussilat42- shura
43- Zukhruf44- Ad Dukhaan
45- Jathiyah46- Ahqaf
47- Muhammad48- Al Fath
49- Hujurat50- Qaf
51- zariyat52- Tur
53- Najm54- Al Qamar
55- Rahman56- Waqiah
57- Hadid58- Mujadilah
59- Al Hashr60- Mumtahina
61- Saff62- Jumuah
63- Munafiqun64- Taghabun
65- Talaq66- Tahrim
67- Mulk68- Qalam
69- Al-Haqqah70- Maarij
71- Nuh72- Jinn
73- Muzammil74- Muddathir
75- Qiyamah76- Insan
77- Mursalat78- An Naba
79- Naziat80- Abasa
81- Takwir82- Infitar
83- Mutaffifin84- Inshiqaq
85- Buruj86- Tariq
87- Al Ala88- Ghashiya
89- Fajr90- Al Balad
91- Shams92- Lail
93- Duha94- Sharh
95- Tin96- Al Alaq
97- Qadr98- Bayyinah
99- Zalzalah100- Adiyat
101- Qariah102- Takathur
103- Al Asr104- Humazah
105- Al Fil106- Quraysh
107- Maun108- Kawthar
109- Kafirun110- Nasr
111- Masad112- Ikhlas
113- Falaq114- An Nas