Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mursalat ayat 32 - المُرسَلات - Page - Juz 29
﴿إِنَّهَا تَرۡمِي بِشَرَرٖ كَٱلۡقَصۡرِ ﴾
[المُرسَلات: 32]
﴿إنها ترمي بشرر كالقصر﴾ [المُرسَلات: 32]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú (Iná náà) yóò máa ju ẹ̀tapàrà (rẹ̀ sókè t’ó máa dà) bí pẹ̀tẹ́ẹ̀sì |