Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 4 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿فَٱلسَّٰبِقَٰتِ سَبۡقٗا ﴾
[النَّازعَات: 4]
﴿فالسابقات سبقا﴾ [النَّازعَات: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún búra pẹ̀lú àwọn mọlāika t’ó máa ṣíwájú ẹ̀mí àwọn onígbàgbọ́ òdodo wọnú Ọgbà Ìdẹ̀ra tààrà |