Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 9 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿كِتَٰبٞ مَّرۡقُومٞ ﴾ 
[المُطَففين: 9]
﴿كتاب مرقوم﴾ [المُطَففين: 9]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwé tí wọ́n ti kọ iṣẹ́ aburú ẹ̀dá sínú rẹ̀ (tí wọ́n sì fi pamọ́ sínú ilẹ̀ keje ni Sijjīn) |