Quran with Yoruba translation - Surah Al-Inshiqaq ayat 7 - الانشِقَاق - Page - Juz 30
﴿فَأَمَّا مَنۡ أُوتِيَ كِتَٰبَهُۥ بِيَمِينِهِۦ ﴾
[الانشِقَاق: 7]
﴿فأما من أوتي كتابه بيمينه﴾ [الانشِقَاق: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ní ti ẹni tí wọ́n bá fún ní ìwé iṣẹ́ rẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ |