Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘la ayat 13 - الأعلى - Page - Juz 30
﴿ثُمَّ لَا يَمُوتُ فِيهَا وَلَا يَحۡيَىٰ ﴾
[الأعلى: 13]
﴿ثم لا يموت فيها ولا يحيا﴾ [الأعلى: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, kò níí kú sínú rẹ̀, kò sì níí ṣẹ̀mí (àlàáfíà) |