Quran with Yoruba translation - Surah Al-Balad ayat 6 - البَلَد - Page - Juz 30
﴿يَقُولُ أَهۡلَكۡتُ مَالٗا لُّبَدًا ﴾
[البَلَد: 6]
﴿يقول أهلكت مالا لبدا﴾ [البَلَد: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó (sì) ń wí pé: "Èmi ti bàná dúkìá ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ (láti fi tako Ànábì s.a.w) |