Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 62 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالَ إِنَّكُمۡ قَوۡمٞ مُّنكَرُونَ ﴾
[الحِجر: 62]
﴿قال إنكم قوم منكرون﴾ [الحِجر: 62]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì Lūt) sọ pé: “Dájúdájú ẹ̀yin jẹ́ àjòjì ènìyàn.” |