Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 63 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالُواْ بَلۡ جِئۡنَٰكَ بِمَا كَانُواْ فِيهِ يَمۡتَرُونَ ﴾
[الحِجر: 63]
﴿قالوا بل جئناك بما كانوا فيه يمترون﴾ [الحِجر: 63]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “Rárá, a wá sọ́dọ̀ rẹ nítorí ohun tí wọ́n ń ṣeyèméjì nípa rẹ̀ |