Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 4 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿وَيُنذِرَ ٱلَّذِينَ قَالُواْ ٱتَّخَذَ ٱللَّهُ وَلَدٗا ﴾
[الكَهف: 4]
﴿وينذر الذين قالوا اتخذ الله ولدا﴾ [الكَهف: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti nítorí kí (Ànábì) lè ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn t’ó wí pé: “Allāhu mú ẹnì kan ní ọmọ.” |