Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 41 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَٱذۡكُرۡ فِي ٱلۡكِتَٰبِ إِبۡرَٰهِيمَۚ إِنَّهُۥ كَانَ صِدِّيقٗا نَّبِيًّا ﴾
[مَريَم: 41]
﴿واذكر في الكتاب إبراهيم إنه كان صديقا نبيا﴾ [مَريَم: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mú (ìtàn) ’Ibrọ̄hīm wá sí ìrántí (bí ó ṣe) wà nínú al-Ƙur’ān. Dájúdájú ó jẹ́ olódodo pọ́nńbélé, (ó sì jẹ́) Ànábì |