Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 40 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿إِنَّا نَحۡنُ نَرِثُ ٱلۡأَرۡضَ وَمَنۡ عَلَيۡهَا وَإِلَيۡنَا يُرۡجَعُونَ ﴾
[مَريَم: 40]
﴿إنا نحن نرث الأرض ومن عليها وإلينا يرجعون﴾ [مَريَم: 40]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa l’A máa jogún ilẹ̀ àti àwọn t’ó ń bẹ lórí rẹ̀. Ọ̀dọ̀ Wa sì ni wọn yóò da yín padà sí |