Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 38 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا ٱلۡوَعۡدُ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 38]
﴿ويقولون متى هذا الوعد إن كنتم صادقين﴾ [الأنبيَاء: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sì ń wí pé: “Ìgbà wo ni ìlérí yìí yóò ṣẹ ná, tí ẹ bá jẹ́ olódodo?” |