Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 67 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿مُسۡتَكۡبِرِينَ بِهِۦ سَٰمِرٗا تَهۡجُرُونَ ﴾
[المؤمنُون: 67]
﴿مستكبرين به سامرا تهجرون﴾ [المؤمنُون: 67]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀ sì ń fi Kaaba ṣègbéraga, ẹ tún ń fi òru yín sọ ìsọkúsọ (nípa al-Ƙur’ān) |