Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 124 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿إِذۡ قَالَ لَهُمۡ أَخُوهُمۡ هُودٌ أَلَا تَتَّقُونَ ﴾
[الشعراء: 124]
﴿إذ قال لهم أخوهم هود ألا تتقون﴾ [الشعراء: 124]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí arákùnrin wọn, (Ànábì) Hūd, sọ pé: “Ṣé ẹ ò níí bẹ̀rù (Allāhu) ni |