Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 71 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا ٱلۡوَعۡدُ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ ﴾
[النَّمل: 71]
﴿ويقولون متى هذا الوعد إن كنتم صادقين﴾ [النَّمل: 71]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n ń wí pé: “Ìgbà wo ni àdéhùn yìí yóò ṣẹ tí ẹ bá jẹ́ olódodo.” |