Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 70 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿وَلَا تَحۡزَنۡ عَلَيۡهِمۡ وَلَا تَكُن فِي ضَيۡقٖ مِّمَّا يَمۡكُرُونَ ﴾
[النَّمل: 70]
﴿ولا تحزن عليهم ولا تكن في ضيق مما يمكرون﴾ [النَّمل: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Má ṣe banújẹ́ nítorí wọn. Má sì jẹ́ kí ohun tí wọ́n ń dá ní ète kó ìnira bá ọ |