Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 72 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿قُلۡ عَسَىٰٓ أَن يَكُونَ رَدِفَ لَكُم بَعۡضُ ٱلَّذِي تَسۡتَعۡجِلُونَ ﴾
[النَّمل: 72]
﴿قل عسى أن يكون ردف لكم بعض الذي تستعجلون﴾ [النَّمل: 72]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Ó lè jẹ́ pé apá kan ohun tí ẹ̀ ń wá pẹ̀lú ìkánjú ti súnmọ́ yín tán.” |