Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 59 - العَنكبُوت - Page - Juz 21
﴿ٱلَّذِينَ صَبَرُواْ وَعَلَىٰ رَبِّهِمۡ يَتَوَكَّلُونَ ﴾
[العَنكبُوت: 59]
﴿الذين صبروا وعلى ربهم يتوكلون﴾ [العَنكبُوت: 59]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn ni) àwọn t’ó ṣe sùúrù. Olúwa wọn sì ni wọ́n ń gbáralé |