Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 108 - آل عِمران - Page - Juz 4
﴿تِلۡكَ ءَايَٰتُ ٱللَّهِ نَتۡلُوهَا عَلَيۡكَ بِٱلۡحَقِّۗ وَمَا ٱللَّهُ يُرِيدُ ظُلۡمٗا لِّلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[آل عِمران: 108]
﴿تلك آيات الله نتلوها عليك بالحق وما الله يريد ظلما للعالمين﴾ [آل عِمران: 108]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwọ̀nyí ni àwọn āyah Allāhu, tí À ń ké e fún ọ pẹ̀lú òdodo. Allāhu kò sì gbèrò àbòsí kan sí gbogbo ẹ̀dá |