Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 141 - آل عِمران - Page - Juz 4
﴿وَلِيُمَحِّصَ ٱللَّهُ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَيَمۡحَقَ ٱلۡكَٰفِرِينَ ﴾
[آل عِمران: 141]
﴿وليمحص الله الذين آمنوا ويمحق الكافرين﴾ [آل عِمران: 141]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé (ó tún rí bẹ́ẹ̀) nítorí kí Allāhu lè ṣàfọ̀mọ́ àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo àti nítorí kí Ó lè run àwọn aláìgbàgbọ́ |