Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 189 - آل عِمران - Page - Juz 4
﴿وَلِلَّهِ مُلۡكُ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۗ وَٱللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيۡءٖ قَدِيرٌ ﴾
[آل عِمران: 189]
﴿ولله ملك السموات والأرض والله على كل شيء قدير﴾ [آل عِمران: 189]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ti Allāhu ni ìjọba àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀. Allāhu sì ni Alágbára lórí gbogbo n̄ǹkan |