Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ahzab ayat 70 - الأحزَاب - Page - Juz 22
﴿يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ ٱتَّقُواْ ٱللَّهَ وَقُولُواْ قَوۡلٗا سَدِيدٗا ﴾
[الأحزَاب: 70]
﴿ياأيها الذين آمنوا اتقوا الله وقولوا قولا سديدا﴾ [الأحزَاب: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, ẹ bẹ̀rù Allāhu. Kí ẹ sì sọ ọ̀rọ̀ òdodo |