Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 173 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَإِنَّ جُندَنَا لَهُمُ ٱلۡغَٰلِبُونَ ﴾
[الصَّافَات: 173]
﴿وإن جندنا لهم الغالبون﴾ [الصَّافَات: 173]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé dájúdájú àwọn ọmọ ogun Wa, àwọn kúkú ni olùborí |