Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 62 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿أَذَٰلِكَ خَيۡرٞ نُّزُلًا أَمۡ شَجَرَةُ ٱلزَّقُّومِ ﴾
[الصَّافَات: 62]
﴿أذلك خير نـزلا أم شجرة الزقوم﴾ [الصَّافَات: 62]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ǹjẹ́ ìyẹn l’ó lóore jùlọ ní ibùdésí ni tàbí igi zaƙūm (igi ẹlẹ́gùn-ún) |