Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 55 - الزُّمَر - Page - Juz 24
﴿وَٱتَّبِعُوٓاْ أَحۡسَنَ مَآ أُنزِلَ إِلَيۡكُم مِّن رَّبِّكُم مِّن قَبۡلِ أَن يَأۡتِيَكُمُ ٱلۡعَذَابُ بَغۡتَةٗ وَأَنتُمۡ لَا تَشۡعُرُونَ ﴾
[الزُّمَر: 55]
﴿واتبعوا أحسن ما أنـزل إليكم من ربكم من قبل أن يأتيكم العذاب﴾ [الزُّمَر: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí ẹ sì tẹ̀lé ohun tí ó dára jùlọ tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ fun yín láti ọ̀dọ̀ Olúwa yín ṣíwájú kí ìyà náà tó wá ba yín ní òjijì, nígbà tí ẹ̀yin kò níí fura |